Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Belgium

  • Jabbeke, Belgium​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ Bíbélì ní ibùdókọ̀ kan lójú ọ̀nà E40 Trans-European Motorway

Ìsọfúnni Ṣókí—Belgium

  • 11,698,000—Iye àwọn èèyàn
  • 26,424—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 338—Iye àwọn ìjọ
  • 449—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún