Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Australia

  • Wollongong , New South Wales, Australia​—Wọ́n ń fún ẹnì kan ní ìwé ìkésíni sí àwọn ìpàdé wa

Ìsọfúnni Ṣókí—Australia

  • 26,636,000—Iye àwọn èèyàn
  • 71,188—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 726—Iye àwọn ìjọ
  • 379—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

BÁ A ṢE Ń RAN ARÁ ÌLÚ LỌ́WỌ́

Wọ́n Ń Tu Àwọn Arúgbó Nínú, Wọ́n sì Ń Fún Wọn Nírètí

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń lọ ṣèbẹ̀wò sí ilé tí wọ́n ti ń tọ́jú arúgbó ní Ọsirélíà.

IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Wíwàásù ní Agbègbè Àdádó​—Ọsirélíà

Wo bí ìdílé Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan ṣe gbádùn ọ̀sẹ̀ alárinrin tí wọ́n fi rìnrìn-àjò lọ sí ìgbèríko kan nílẹ̀ Ọsirélíà kí wọ́n lè lọ kọ́ àwọn èèyàn ibẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.