Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Angola

  • Benguela, Angola​—Wọ́n ń kọ́ ẹnì kan lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Angola

Ìsọfúnni Ṣókí—Angola

  • 36,149,000—Iye àwọn èèyàn
  • 169,960—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 2,567—Iye àwọn ìjọ
  • 221—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ

A Pèsè Ìrànwọ́ Fáwọn Tí Àjálù Ṣẹlẹ̀ Sí

Lọ́dún iṣẹ́ ìsìn 2020, àrùn Corona àtàwọn àjálù míì mú kí nǹkan nira fún ọ̀pọ̀ àwọn ará wa. Báwo la ṣe ràn wọ́n lọ́wọ́?

ÌRÒYÌN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Ṣèrànwọ́ Fáwọn Tó Fojú Winá Jàǹbá Omíyalé ní Àǹgólà

Lọ́jọ́ kejì ọjọ́ tí jàǹbá omíyalé ṣẹlẹ̀ ní agbègbè Benguela ní Àǹgólà, a ṣètò ìgbìmọ̀ kan láti ṣèrànwọ́ fáwọn tí àjálù náà bá.