Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Armenia

Ìsọfúnni Ṣókí—Armenia

  • 3,103,000—Iye àwọn èèyàn
  • 11,313—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 134—Iye àwọn ìjọ
  • 277—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Bó Ṣe Di Pé Ìjọba Àméníà Fọwọ́ sí I Pé Èèyàn Lẹ́tọ̀ọ́ Láti Sọ Pé Ẹ̀rí Ọkàn Ò Jẹ́ Kóun Ṣiṣẹ́ Ológun

Ìtàn ohun tó ti ṣẹlẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ àwọn tí ẹ̀rí ọkàn ò jẹ́ kí wọ́n ṣiṣẹ́ ológun ní Àméníà jẹ́ ká rí i bí àwọn ẹjọ́ tí ECHR dá ṣe nípa pàtàkì lórí ọwọ́ tí ìjọba fi ń mú àwọn tí ẹ̀rí ọkàn ò jẹ́ kí wọ́n ṣiṣẹ́ ológun.

ÌRÒYÌN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tó Kọ́kọ́ Ṣe Iṣẹ́ Àṣesìnlú Lórílẹ̀-èdè Àméníà Ti Parí Ẹ̀

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Àméníà ń ṣe ojúṣe wọn fún ìjọba lọ́nà tó máa ṣe orílẹ̀-èdè wọn àtàwọn aráàlú láǹfààní, láì ṣohun tí ò bá ẹ̀rí ọkàn wọn mu.

ÌRÒYÌN

Ìjọba Àméníà Dá Àwọn tí Ẹ̀rí Ọkàn Ò Jẹ́ Kí Wọ́n Ṣiṣẹ́ Ológun Sílẹ̀

Báwo ni ìpinnu mánigbàgbé kan tí ilé ẹjọ́ ṣe ṣe mú kí ìjọba dá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà yìí sílẹ̀?

ILÉ ÌṢỌ́

Ilé Ẹjọ́ Ilẹ̀ Yúróòpù Gbèjà Ẹ̀tọ́ Ẹni Tí Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ̀ Kò Jẹ́ Kó Ṣiṣẹ́ Ológun

Ká nípa ẹjọ́ mánigbàgbé tí Ilẹ̀ Yúróòpù máa máa tẹ̀ lé báyìí.