Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Jason Worilds: Èèyàn Ò Lè Pàdánù Ohunkóhun Tó Bá Fayé Ẹ̀ Sin Jèhófà

Jason Worilds: Èèyàn Ò Lè Pàdánù Ohunkóhun Tó Bá Fayé Ẹ̀ Sin Jèhófà

Lásìkò tí Jason tó jẹ́ gbajúgbajà agbábọ́ọ̀lù ń rọ́wọ́ mú nídìí iṣẹ́ bọ́ọ̀lù gbígbá, ó pinnu láti fi iṣẹ́ náà sílẹ̀ kó lè fi ire Ìjọba Ọlọ́run sípò àkọ́kọ́.