Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Kọ́ Ọmọ Rẹ

A fi èdè tó rọrùn láti lóye kọ àwọn ìtàn Bíbélì yìí káwọn òbí lè fi kọ́ àwọn ọmọ wọn láwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì látinú Bíbélì. A kọ wọ́n lọ́nà táwọn òbí á fi lè máa kà wọ́n pẹ̀lú àwọn ọmọ wọn.