Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Eré Ìkẹ́kọ̀ọ́

Wa eré ìkẹ́kọ̀ọ́ jáde, tẹ̀ ẹ́, kó o sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn ibi tí Bíbélì sọ̀rọ̀ wọn àti àwọn èèyàn inú Bíbélì. Dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà níbẹ̀, kó o sì ní kí ẹnì kan nínú ìdílé yín wò bóyá o gbà wọ́n.