Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

IBI TÍ MO KỌ ÈRÒ MI SÍ

Wò Ó Bóyá Ọ̀rọ̀ Ìfẹ́ Ti Wọ̀ Ọ́ Lóòótọ́

Ibi tó o lè kọ èrò rẹ sí kó o má bàa máa ṣe ẹ́ bíi pé ọ̀rọ̀ ìfẹ́ ti wọ àjọṣe ìwọ àti ẹnì kan, láìmọ̀ pé kò ṣe ẹnì kejì bẹ́ẹ̀.