Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ

Mọrírì Àwọn Ohun Mímọ́!

Kẹ́kọ̀ọ́ látinú ìtàn Jékọ́bù àti Ísọ̀. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!