Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KẸ́KỌ̀Ọ́ LÁRA ÀWỌN Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Hananáyà, Míṣáẹ́lì, àti Asaráyà

Hananáyà, Míṣáẹ́lì, àti Asaráyà

Lo eré yìí láti kẹ́kọ̀ọ́ lára Hananáyà, Míṣáẹ́lì, àti Asaráyà tí wọ́n jẹ́ ọ̀rẹ́ Jèhófà.

Ẹ̀yin òbí, ẹ ka Dáníẹ́lì 1:3-7 àtàwọn ẹsẹ míì nínú orí 3 pẹ̀lú àwọn ọmọ yín, kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀.

Wà á jáde, kó o sì tẹ̀ ẹ́ sórí ìwé.

Tẹ̀ lé àbá tó wà lójú ìwé àkọ́kọ́ láti gé àwọn àwòrán tó wà níbẹ̀, kó o sì tò wọ́n sójú ìwé kejì. Bẹ́ ẹ ṣe ń ṣiṣẹ́ lórí àwòrán yìí, ẹ dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà nínú fídíò náà.