Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé?

Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé?

Ṣé o rò pé . . .

  • inú ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì ni?

  • àbí inú ìmọ̀ ọgbọ́n orí?

  • àbí inú Bíbélì?

Ọ̀KAN LÁRA ÀWỌN TÓ KỌ BÍBÉLÌ SỌ FÚN ỌLỌ́RUN PÉ

“Fún mi ní òye . . . Òtítọ́ ni . . . ọ̀rọ̀ rẹ.”​—Sáàmù 119:144, 160, Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun.

Bíbélì ń dáhùn ìbéèrè ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn.

Ṣé wàá fẹ́ kó dáhùn tìẹ náà?

Ìkànnì jw.org/yo máa ràn ẹ́ lọ́wọ́.

WA àwọn ìwé jáde

ÈWO LÁRA ÀWỌN ÌBÉÈRÈ PÀTÀKÌ YÌÍ LÓ Ń JẸ Ọ́ LỌ́KÀN JÙ LỌ?

Wàá rí ìdáhùn látinú Bíbélì sí àwọn ìbéèrè yìí lórí ìkànnì jw.org/yo.

(Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ › OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ)