Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ‘Ẹ Máa Kéde Ìhìn Rere!’ Ọdún 2024

Friday

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Friday dá lórí Lúùkù 2:10​—‘Ìhìn rere ayọ̀ ńláǹlà, èyí tí gbogbo èèyàn máa ní.’

Saturday

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Saturday dá lórí Sáàmù 96:2​—“Ẹ máa kéde ìhìn rere ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́.”

Sunday

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Sunday dá lórí Mátíù 24:14​—“. . . nígbà náà ni òpin yóò dé.”

Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá Sí Àpéjọ Yìí Mọ̀

Ohun tá a fẹ́ kí àwọn tó wá sí àpéjọ yìí mọ̀.

O Tún Lè Wo

NÍPA WA

Lọ Sí Àpéjọ tọdún 2024​—‘Ẹ Máa Kéde Ìhìn Rere!’

A fẹ́ kó o wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe.

ÀPÉJỌ

A Fẹ́ Kó O Wá: Àpéjọ Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti 2024, ‘Ẹ Máa Kéde Ìhìn Rere!’

A pè ẹ́ wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe.

ÀPÉJỌ

Ìtọ́wò Fídíò Ìtàn Bíbélì: Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé

Wo ìtọ́wò abala kìíní fídíò Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù. A máa wo abala yìí ní àpéjọ agbègbè àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tọdún 2024.