Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2023-2024 Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe

Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run!

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn nǹkan tá a máa gbádùn ní àárọ̀ àti ọ̀sán àpéjọ àyíká tí aṣojú ẹ̀ka ọ́fíìsì máa bá wa ṣe.

Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí

A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí bá a ṣe ń bá àpéjọ náà lọ.