Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé ti Ọdún 2023

Wàá rí ìròyìn nípa iṣẹ́ ìwàásù tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe kárí ayé láti September 2022 sí August 2023.

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2023

Ìròyìn ọdọọdún yìí á jẹ́ kó o mọ báwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ṣiṣẹ́ kára ká lè wàásù ìhìn rere kárí ayé.

Ìròyìn Orílẹ̀-èdè àti ti Ìpínlẹ̀ ti Ọdún 2023

Ìròyìn yìí á jẹ́ kó o mọ iye àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, iye àwọn tó ṣèrìbọmi, iye àwọn tó wá sí Ìrántí Ikú Kristi àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

O Tún Lè Wo

ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Mélòó Ló Wà Kárí Ayé?

Wo bá a ṣe máa ń ka iye wa nínú àwọn ìjọ wa kárí ayé.

ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ

Kí Nìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Ń Lọ Láti Ilé Dé Ilé?

Kọ́ nípa ohun tí Jésù sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ pé kí wọ́n máa ṣe.

ÀWỌN Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ TÁ A LÈ LÒ LÓDE Ẹ̀RÍ

Ta Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló fẹ́ mọ irú ẹni tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà jẹ́. Jọ̀wọ́, wo fídíò tí àwa fúnra wa ṣe yìí, kó o lè túbọ̀ mọ̀ wá.

NÍPA WA

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Mọ̀ nípa ẹgbẹ́ ará wa kárí ayé.

NÍPA WA

Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Níbi gbogbo kárí ayé làwọn èèyàn ti mọ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí wọ́n máa ń ṣe fáwọn èèyàn lọ́fẹ̀ẹ́. Wo bí wọ́n ṣe máa ń ṣe é.