Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?

Kí Ni Ìfẹ́ Tòótọ́?

Ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ni Liz àti Megan, àwọn méjèèjì sì ń wa ẹni tí wọ́n máa fẹ́. Àmọ́ ọ̀nà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ làwọn méjèèjì gbà ń wá ẹni tí wọ́n máa fẹ́.